Ìtàn Jónà—Ẹ̀kọ́ Nípa Ìgboyà àti Àánú
Jèhófà rán wòlíì Jónà pé kó lọ kéde ìdájọ́ sórí ìlú Nínéfè tó jẹ́ olú ìlú Ásíríà, àmọ́ Jónà kọ̀ láti jíṣẹ́ náà; ohun tó ṣẹlẹ̀ tẹ̀ lé e jẹ́ kí Jónà rí ìdí téèyàn fi gbọ́dọ̀ jẹ́ onígboyà àti aláàánú.
O Tún Lè Wo
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Jónà Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àwọn Àṣìṣe Rẹ̀
Ǹjẹ́ iṣẹ́ tí Jèhófà ní kó o ṣe ti bà ọ́ lẹ́rù rí bíi ti Jónà? Kí ni ìtàn Jónà kọ́ wa nípa sùúrù àti àánú Jèhófà.
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Jónà Kọ́ Ìdí Tó Fi Yẹ Kó Jẹ́ Aláàánú
Báwo ni ìtàn Jónà ṣe lè mú ká fara balẹ̀ ṣàyẹ̀wò irú ẹni tá a jẹ́ gan-an?
BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN