Àtẹ Àwọn Ìwé Inú Bíbélì
Àwọn Ìwé inú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù Ṣáájú Sànmánì (Kristẹni)
ORÚKỌ ÌWÉ |
ÒǸKỌ̀WÉ |
IBI TÍ A TI KỌ Ọ́ |
ÌGBÀ TÓ PARÍ (Ṣ.S.K.) |
ÀKÓKÒ TÓ GBÀ (Ṣ.S.K.) |
---|---|---|---|---|
Jẹ́nẹ́sísì |
Mósè |
Aginjù |
1513 |
“Ní ìbẹ̀rẹ̀” sí 1657 |
Ẹ́kísódù |
Mósè |
Aginjù |
1512 |
1657 sí 1512 |
Léfítíkù |
Mósè |
Aginjù |
1512 |
Oṣù kan (1512) |
Nọ́ńbà |
Mósè |
Aginjù àti Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù |
1473 |
1512 sí 1473 |
Diutarónómì |
Mósè |
Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù |
1473 |
Oṣù méjì (1473) |
Jóṣúà |
Jóṣúà |
Kénáánì |
n. 1450 |
1473 sí n. 1450 |
Àwọn Onídàájọ́ |
Sámúẹ́lì |
Ísírẹ́lì |
n. 1100 |
n. 1450 sí n. 1120 |
Rúùtù |
Sámúẹ́lì |
Ísírẹ́lì |
n. 1090 |
11 ọdún ìṣàkóso Àwọn Onídàájọ́ |
1 Sámúẹ́lì |
Sámúẹ́lì; Gádì; Nátánì |
Ísírẹ́lì |
n. 1078 |
n. 1180 sí 1078 |
2 Sámúẹ́lì |
Gádì; Nátánì |
Ísírẹ́lì |
n. 1040 |
1077 sí n. 1040 |
1 Àwọn Ọba |
Jeremáyà |
Júdà |
580 |
n. 1040 sí 911 |
2 Àwọn Ọba |
Jeremáyà |
Júdà àti Íjíbítì |
580 |
n. 920 sí 580 |
1 Kíróníkà |
Ẹ́sírà |
Jerúsálẹ́mù (?) |
n. 460 |
Lẹ́yìn 1 Kíróníkà 9:44: n. 1077 sí 1037 |
2 Kíróníkà |
Ẹ́sírà |
Jerúsálẹ́mù (?) |
n. 460 |
n. 1037 sí 537 |
Ẹ́sírà |
Ẹ́sírà |
Jerúsálẹ́mù |
n. 460 |
537 sí n. 467 |
Nehemáyà |
Nehemáyà |
Jerúsálẹ́mù |
l. 443 |
456 sí l. 443 |
Ẹ́sítà |
Módékáì |
Ṣúṣánì, Élámù |
n. 475 |
493 sí n. 475 |
Jóòbù |
Mósè |
Aginjù |
n. 1473 |
Ó ju 140 ọdún láti 1657 sí 1473 |
Sáàmù |
Dáfídì àti àwọn míì |
n. 460 |
||
Òwe |
Sólómọ́nì; Ágúrì; Lémúẹ́lì |
Jerúsálẹ́mù |
n. 717 |
|
Oníwàásù |
Sólómọ́nì |
Jerúsálẹ́mù |
ṣ. 1000 |
|
Orin Sólómọ́nì |
Sólómọ́nì |
Jerúsálẹ́mù |
n. 1020 |
|
Àìsáyà |
Àìsáyà |
Jerúsálẹ́mù |
l. 732 |
n. 778 sí l. 732 |
Jeremáyà |
Jeremáyà |
Júdà; Íjíbítì |
580 |
647 sí 580 |
Ìdárò |
Jeremáyà |
Nítòsí Jerúsálẹ́mù |
607 |
|
Ìsíkíẹ́lì |
Ìsíkíẹ́lì |
Bábílónì |
n. 591 |
613 sí n. 591 |
Dáníẹ́lì |
Dáníẹ́lì |
Bábílónì |
n. 536 |
618 sí n. 536 |
Hósíà |
Hósíà |
Samáríà (Agbègbè) |
l. 745 |
ṣ. 804 sí l. 745 |
Jóẹ́lì |
Jóẹ́lì |
Júdà |
n. 820 (?) |
|
Émọ́sì |
Émọ́sì |
Júdà |
n. 804 |
|
Ọbadáyà |
Ọbadáyà |
n. 607 |
||
Jónà |
Jónà |
n. 844 |
||
Míkà |
Míkà |
Júdà |
ṣ. 717 |
n. 777 si 717 |
Náhúmù |
Náhúmù |
Júdà |
ṣ. 632 |
|
Hábákúkù |
Hábákúkù |
Júdà |
n. 628 (?) |
|
Sefanáyà |
Sefanáyà |
Júdà |
ṣ. 648 |
|
Hágáì |
Hágáì |
Jerúsálẹ́mù |
520 |
112 ọjọ́ (520) |
Sekaráyà |
Sekaráyà |
Jerúsálẹ́mù |
518 |
520 sí 518 |
Málákì |
Málákì |
Jerúsálẹ́mù |
l. 443 |
Àwọn Ìwé inú Ìwé Mímọ́ Lédè Gíríìkì Tí A Kọ ní Sànmánì (Kristẹni)
ORÚKỌ ÌWÉ |
ÒǸKỌ̀WÉ |
IBI TÍ A TI KỌ Ọ́ |
ÌGBÀ TÓ PARÍ (S.K.) |
ÀKÓKÒ TÓ GBÀ |
---|---|---|---|---|
Mátíù |
Mátíù |
Ísírẹ́lì |
n. 41 |
2 Ṣ.S.K. sí 33 S.K. |
Máàkù |
Máàkù |
Róòmù |
n. 60 sí 65 |
29 sí 33 S.K. |
Lúùkù |
Lúùkù |
Kesaríà |
n. 56 sí 58 |
3 Ṣ.S.K. sí 33 S.K. |
Jòhánù |
Àpọ́sítélì Jòhánù |
Éfésù tàbí nítòsí |
n. 98 |
Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣáájú, 29 sí 33 S.K. |
Ìṣe |
Lúùkù |
Róòmù |
n. 61 |
33 sí n. 61 S.K. |
Róòmù |
Pọ́ọ̀lù |
Kọ́ríńtì |
n. 56 |
|
1 Kọ́ríńtì |
Pọ́ọ̀lù |
Éfésù |
n. 55 |
|
2 Kọ́ríńtì |
Pọ́ọ̀lù |
Makedóníà |
n. 55 |
|
Gálátíà |
Pọ́ọ̀lù |
Kọ́ríńtì tàbí Áńtíókù ti Síríà |
n. 50 sí 52 |
|
Éfésù |
Pọ́ọ̀lù |
Róòmù |
n. 60 sí 61 |
|
Fílípì |
Pọ́ọ̀lù |
Róòmù |
n. 60 sí 61 |
|
Kólósè |
Pọ́ọ̀lù |
Róòmù |
c. 60 sí 61 |
|
1 Tẹsalóníkà |
Pọ́ọ̀lù |
Kọ́ríńtì |
n. 50 |
|
2 Tẹsalóníkà |
Pọ́ọ̀lù |
Kọ́ríńtì |
n. 51 |
|
1 Tímótì |
Pọ́ọ̀lù |
Makedóníà |
n. 61 sí 64 |
|
2 Tímótì |
Pọ́ọ̀lù |
Róòmù |
n. 65 |
|
Títù |
Pọ́ọ̀lù |
Makedóníà (?) |
n. 61 sí 64 |
|
Fílémónì |
Pọ́ọ̀lù |
Róòmù |
n. 60 sí 61 |
|
Hébérù |
Pọ́ọ̀lù |
Róòmù |
n. 61 |
|
Jémíìsì |
Jémíìsì (Àbúrò Jésù) |
Jerúsálẹ́mù |
ṣ. 62 |
|
1 Pétérù |
Pétérù |
Bábílónì |
n. 62 sí 64 |
|
2 Pétérù |
Pétérù |
Bábílónì (?) |
n. 64 |
|
1 Jòhánù |
Àpọ́sítélì Jòhánù |
Éfésù tàbí nítòsí |
n. 98 |
|
2 Jòhánù |
Àpọ́sítélì Jòhánù |
Éfésù tàbí nítòsí |
n. 98 |
|
3 Jòhánù |
Àpọ́sítélì Jòhánù |
Éfésù tàbí nítòsí |
n. 98 |
|
Júùdù |
Júùdù (Àbúrò Jésù)) |
Ísírẹ́lì (?) |
n. 65 |
|
Ìfihàn |
Àpọ́sítélì Jòhánù |
Pátímọ́sì |
n. 96 |
[Orúkọ àwọn òǹkọ̀wé ìwé mélòó kan àti ibi tí a ti kọ wọ́n kò dájú. Ṣe ni a fojú bu ọ̀pọ̀ nínú àwọn déètì náà, àmì náà l. túmọ̀ sí “lẹ́yìn,” n. túmọ̀ sí “nǹkan bí,” ṣ. sì túmọ̀ sí “ṣáájú.”]