December 4-10
JÓÒBÙ 22-24
Orin 49 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ṣé Èèyàn Wúlò fún Ọlọ́run?”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Job 23:13—Báwo ni àpẹẹrẹ Jèhófà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ kọ́wọ́ wa lè tẹ àwọn ohun tá a pinnu láti ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn rẹ̀? (w04 7/15 21-22)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 22:1-22 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 2)
Àsọyé: (5 min.) w21.05 18-19 ¶17-20—Àkòrí: Jèhófà Máa Lò Wá Tá Ò Bá Jẹ́ Kó Sú Wa. (th ẹ̀kọ́ 20)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọ́n Lè Múnú Jèhófà Dùn”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 3 ¶1-3, àwọn àpótí tó wà lójú ìwé 23, 24, 25, 26, àti 27
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 25 àti Àdúrà