Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

December 2-8

SÁÀMÙ 113-118

December 2-8

Orin 127 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Kí La Máa San Pa Dà fún Jèhófà?

(10 min.)

Jèhófà ń dáàbò bò wá, ó ń fi inúure hàn sí wa, ó sì máa ń gbà wá (Sm 116:6-8; w01 1/1 11 ¶13)

A lè fi hàn pé a mọrírì ohun tí Jèhófà ń ṣe fún wa tá a bá ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, tá a sì ń fi ìlànà ẹ̀ sílò nígbèésí ayé wa (Sm 116:12, 14; w09 7/15 29 ¶4-5)

A tún lè san oore Jèhófà tá a bá ń “rú ẹbọ ọpẹ́” sí i (Sm 116:17; w19.11 22-23 ¶9-11)

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 116:15—Àwọn wo làwọn “ẹni ìdúróṣinṣin” Ọlọ́run tí Bíbélì yìí ń sọ? (w12 5/15 22 ¶1-2)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Má Bẹ̀rù Láti Sọ Òótọ́ Ọ̀rọ̀—Ohun Tí Jésù Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 12 kókó 1-2.

5. Má Bẹ̀rù Láti Sọ Òótọ́ Ọ̀rọ̀—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 12 kókó 3-5 àti apá “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 60

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 29 àti Àdúrà