Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Báwo la ṣe lè fara dà á nígbà tí àjálù bá ṣẹlẹ̀?

WO OJÚ ÌWÉ 6 ÀTI 7.

Ǹjẹ́ ìgbà kan máa wà tí àjálù kò ní sí mọ́?

WO OJÚ ÌWÉ 8 ÀTI 9.

Ǹjẹ́ ẹnì kan wà tó lè túmọ̀ àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì?

WO OJÚ ÌWÉ 11 SÍ 13.

Ǹjẹ́ o fẹ́ mọ bó o ṣe lè yan ọ̀rẹ́ tòótọ́?

WO OJÚ ÌWÉ 16 ÀTI 17.

Kí ló túmọ̀ sí nígbà tí Bíbélì sọ pé “ìgbà nínífẹ̀ẹ́ àti ìgbà kíkórìíra” wà?

WO OJÚ ÌWÉ 23 SÍ 25.