Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2020-2021—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
Àsọyé tí aṣojú ẹ̀ka ọ́fíìsì máa sọ wà lára ohun tá a máa gbádùn ní àpéjọ àyíká yìí. Ẹṣin ọ̀rọ̀ àpéjọ náà ni “Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà.”
“Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà”
Àwọn ohun tá a máa gbádùn ní àárọ̀ àti ọ̀sán àpéjọ àyíká tí aṣojú ẹ̀ka ọ́fíìsì máa bá wa ṣe.
Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí ní àpéjọ àyíká yìí.