Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

“Ja Ìjà Rere ti Ìgbàgbọ́”

“Ja Ìjà Rere ti Ìgbàgbọ́”

Wà á jáde:

  1. 1. Nígbà míì kì í rọrùn rárá.

    Kò rọrùn láti dá yàtọ̀ rárá.

    Ọ̀rọ̀ yìí máa ń tojú sú mi.

    Ìgbà míì wà tí mo máa ń sunkún.

    (ṢÁÁJÚ ÈGBÈ)

    Jèhófà gbọ́ ‘gbe ẹkún mi.

    Mo ti wá mọ ohun tó yẹ kí n ṣe.

    Mo wá ka Bíbélì.

    Mo gbọ́ Jèhófà tó ń sọ pé:

    (ÈGBÈ)

    ‘Ọjọ́ náà ti sún mọ́lé,

    Wò ó, kò ní sí igbe ẹkún mọ́.

    Ọjọ́ náà ti sún mọ́lé,

    Ayé tuntun dé tán.

    Ṣáà jólóòótọ́ sí mi.

    Ja ìjà ìgbà-gbọ́

    Jà!

    Màá ràn ẹ́ lọ́wọ́. Jà!’

  2. 2. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ ń fún mi ní agbára.

    Bí ìṣòro bá dé, mo gbẹ́kẹ̀ lé ọ́.

    (ṢÁÁJÚ ÈGBÈ)

    Jèhófà gbọ́ ‘gbe ẹkún mi.

    Mo ti wá mọ ohun tó yẹ kí n ṣe.

    Mo wá ka Bíbélì.

    Mo gbọ́ Jèhófà tó ń sọ pé:

    (ÈGBÈ)

    ‘Ọjọ́ náà ti sún mọ́lé,

    Wò ó, kò ní sí igbe ẹkún mọ́.

    Ọjọ́ náà ti sún mọ́lé,

    Ayé tuntun dé tán.

    Ṣáà jólóòótọ́ sí mi.

    Ja ìjà ìgbà-gbọ́!

    Jà!

    Ja ìjà ìgbà-gbọ́!

    Ja ìjà ìgbà-gbọ́

    Màá ràn ọ́ lọ́wọ́. Jà!’

    (ÀSOPỌ̀)

    ‘Má bẹ̀rù má ṣojo,

    Mo máa dúró tì ẹ́,

    Mo máa ràn ẹ́ lọ́wọ́.’

    (ÈGBÈ)

    ‘Ọjọ́ náà ti sún mọ́lé,

    Wò ó, kò ní sí igbe ẹkún mọ́.

    Ọjọ́ náà ti sún mọ́lé,

    Ayé tuntun dé tán.

    Ṣáà jólóòótọ́ sí mi.

    Mo máa ràn ẹ́ lọ́-wọ́.’