Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àlàáfíà àti Ayọ̀

Tá a bá dojú kọ àwọn ìṣòro ńlá, ó lè máa ṣe wá bíi pé a ò lè láyọ̀ mọ́ tàbí pé a ò lè ní ìfọ̀kànbalẹ̀. Síbẹ̀, Bíbélì ti ran ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lọ́wọ́ láti fara da wàhálà ojoojúmọ́ tó ń bá wọn, ó ti jẹ́ kí ara tù wọ́n, ó sì ti bá wọn mú ẹ̀dùn ọkàn wọn kúrò. Yàtọ̀ síyẹn, ó ti jẹ́ kí ìgbésí ayé wọn nítumọ̀, ó sì ti jẹ́ káyé wọn dáa sí i. Bíbélì lè ran ìwọ náà lọ́wọ́ kó o lè láyọ̀.

JÍ!

Sùúrù Ń Mú Káyé Ẹni Dáa Sí I

A máa jàǹfààní tó pọ̀ tá a bá ń ṣe sùúrù tá a sì ń kápá ìmọ̀lára wa.

JÍ!

Sùúrù Ń Mú Káyé Ẹni Dáa Sí I

A máa jàǹfààní tó pọ̀ tá a bá ń ṣe sùúrù tá a sì ń kápá ìmọ̀lára wa.

Iṣẹ́ àti Owó

Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Àwọn Míì

Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà

Oríṣiríṣi àwọn èèyàn sọ bí ayé wọn ṣe wá nítumọ̀, tí wọ́n sì sún mọ́ Ọlọ́run báyìí.

Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú

Ṣé ẹnì kan tó o fẹ́ràn kú? Ṣé o nílò ìrànlọ́wọ́ láti kojú ẹ̀dùn ọkàn rẹ?

Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀

O lè ní ìgbeyàwó àti ìdílé tó láyọ̀ tó o bá ń fi àwọn ìlànà Bíbélì sílò.

Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́dọ̀ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn

Bíbélì ń ran ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù èèyàn kárí ayé lọ́wọ́ láti rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè pàtàkì nípa ìgbésí ayé. Ṣé ìwọ náà á fẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára wọn?

Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Níbi gbogbo kárí ayé làwọn èèyàn ti mọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí wọ́n máa ń ṣe fáwọn èèyàn lọ́fẹ̀ẹ́. Wo bí wọ́n ṣe máa ń ṣe é.

Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá

O lè mọ̀ sí i nípa Bíbélì tàbí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.