KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI?
Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? (Apá 2)
Orí kẹjọ ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.
Kí ni àwọn nǹkan tí Ìjọba Ọlọ́run ti gbé ṣe? Kí làwọn nǹkan tó máa ṣe lọ́jọ́ iwájú? Kọ́ nípa ohun tí Bíbélì sọ.