Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ

Ohun Tó O Lè Ṣe tí Òbí Ẹ Bá Ń Ṣàìsàn

Ibi tó o lè kọ èrò ẹ sí, kó o lè mọ bí wàá ṣe máa tọ́jú òbí ẹ tó bá ń ṣàìsàn, kó o sì tún tọ́jú ara rẹ.