Ìsọfúnni Ṣókí—Argentina
- 46,045,000—Iye àwọn èèyàn
- 153,751—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 1,938—Iye àwọn ìjọ
- 301—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÒYÌN
A Wàásù Lákànṣe Níbi Térò Pọ̀ sí Nígbà Eré Ìdárayá Òlíńpíìkì Tó Wáyé ní Ajẹntínà Lọ́dún 2018
Nǹkan bí ọgọ́rùn-ún méje ó lé àádọ́rùn-ún (790) ìwé làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà pín lójoojúmọ́ nígbà ìwàásù àkànṣe náà kí àwọn eléré ìdárayá àtàwọn àlejò lè mọ̀ nípa ẹ̀kọ́ Bíbélì.