Ìsọfúnni Ṣókí—Congo, Democratic Republic of
- 98,152,000—Iye àwọn èèyàn
- 257,672—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 4,385—Iye àwọn ìjọ
- 402—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Bá A Ṣe Pèsè Ìrànwọ́ Lọ́dún 2021—A Ò Pa Àwọn Arákùnrin Àtàwọn Arábìnrin Wa Tì
Lọ́dún 2021, a ṣèrànwọ́ fáwọn ará wa láwọn orílẹ̀-èdè kan tí àrùn Corona àtàwọn àjálù míì ti fojú wọn rí màbo.
ÌRÒYÌN
Àwọn Ará ní Àríwá Ìlà Oòrùn Kóńgò Sá Torí Àwọn Tó Ń Jà
Bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó sá kúrò ní Kóńgò ò nílé tara wọn, síbẹ̀ wọ́n ń kóra jọ láti jọ́sìn, wọ́n sì ń fìtara wàásù ìrètí tí Bíbélì jẹ́ kí wọ́n ní fáwọn èèyàn.
ÌRÒYÌN
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣèrànwọ́ Fáwọn tí Ìjà Tó Wáyé Lórílẹ̀-èdè Kóńgò Pa Lára
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣèrànwọ́ fáwọn ará wọn àtàwọn míì tó fara gbá ọ̀rọ̀ ìjà àti ìpakúpa tó wáyé ní àgbègbè Kasai ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira ti Kóńgò.
IṢẸ́ ÌTẸ̀WÉ
Wọ́n Pín Ìwé Tó Ṣàlàyé Bíbélì Lórílẹ̀-Èdè Congo
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà yọ̀ǹda ara wa lóṣooṣù láti kó Bíbélì àtàwọn ìwé tó ṣàlàyé Bíbélì lọ fún àwọn èèyàn ní Orílẹ̀-èdè Congo.