Ìsọfúnni Ṣókí—Guadeloupe
- 396,000—Iye àwọn èèyàn
- 8,488—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 118—Iye àwọn ìjọ
- 47—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÒYÌN
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Túbọ̀ Ń Ṣètò Ìrànwọ́ Lẹ́yìn Ìjì Líle Tó Jà
Àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sọ̀rọ̀ nípa ìrànwọ́ tí wọ́n ń ṣe fáwọn tí ìjì líle Hurricane Irma àti Hurricane Maria ṣèpalára fún àti bí wọ́n ṣe ń fi ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tù wọ́n nínú.