Ìsọfúnni Ṣókí—Kyrgyzstan
- 7,038,000—Iye àwọn èèyàn
- 5,167—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 86—Iye àwọn ìjọ
- 1,387—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Ohun Gbogbo Ṣeé Ṣe Lọ́dọ̀ Jèhófà
Ọ̀rọ̀ tí arábìnrin kan sọ nínú bọ́ọ̀sì lórílẹ̀-èdè Kyrgyzstan ló yí ìgbésí ayé àwọn tọkọtaya kan padà.
JÍ!
Ìbẹ̀wò sí Orílẹ̀-èdè Kyrgyzstan
Àwọn èèyàn ìlú Kyrgyzstan kóni mọ́ra wọ́n sì ń bọ̀wọ̀ fúnni. Àwọn àṣà wo ní wọ́n máa ń dá nínú ọ̀pọ̀ ìdílé níbẹ̀?