Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Sri Lanka

  • Hatton, Sri Lanka​—Wọ́n ń fún ẹnì kan tó ń ká tíì ní ìwé pẹlẹbẹ tó dá lórí Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—Sri Lanka

  • 22,181,000—Iye àwọn èèyàn
  • 7,003—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 98—Iye àwọn ìjọ
  • 3,195—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

Ohun Tó Ṣẹ́ Kù Níbì Kan Ń Dí Àìtó Àwọn Míì

Báwo la ṣe ń ṣètìlẹyìn fáwọn ará wa tó ń gbé láwọn orílẹ̀-èdè tí nǹkan ò ti ṣẹnuure?

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣe Àkànṣe Àpéjọ Fúngbà Àkọ́kọ́ ní Siri Láńkà

Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ló wá láti orílẹ̀-èdè méje ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ láti wá bá àwọn ará wọn lọ́kùnrin lóbìnrin nílùú Colombo ṣe àkànṣe àpéjọ. Ìgbà àkọ́kọ́ tírú ẹ̀ máa wáyé nìyẹn ní Siri Láńkà.

Iwe Odoodun Awa Elerii Jehofa​—2015

Iyasimimo Eka Ofiisi Orile-Ede Siri Lanka

A se atagba fidio ohun to n lo nigba itoleseese naa. Awon ara si ri ara won lati ibi otooto ti won wa.