Ìsọfúnni Ṣókí—New Caledonia
- 271,000—Iye àwọn èèyàn
- 2,693—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 34—Iye àwọn ìjọ
- 103—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÒYÌN
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣètò Ìrànwọ́ fún Àwọn Tí Ìjì Cyclone Pam Ṣe Lọ́ṣẹ́
Àwọn Ẹlẹ́rìí ń pèsè ìrànwọ́ fún àwọn tí ìjì Tropical Cyclone Pam ṣe lọ́ṣẹ́ wọ́n sì ń fi Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tù wọ́n nínú.