Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Portugal

  • Sintra, Portugal​—Wọ́n ń wàásù láti-ilé-dé-ilé

Ìsọfúnni Ṣókí—Portugal

  • 9,974,000—Iye àwọn èèyàn
  • 52,498—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 653—Iye àwọn ìjọ
  • 192—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Bí Iṣẹ́ Fífúnrúgbìn Ìjọba Náà Ṣe Bẹ̀rẹ̀ Lórílẹ̀-Èdè Pọ́túgà

Àwọn ìṣòro wo làwọn tó kọ́kọ́ wàásù níbẹ̀ borí?

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Jèhófà Fi Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Hàn sí Wa Lónírúurú Ọ̀nà

Douglas àti Mary Guest jọlá inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run nígbà tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ aṣáájú-ọ̀nà ní Kánádà àtìgbà tí wọ́n ṣiṣẹ́ míṣọ́nnárì ní Bìràsílì àti Pọ́túgàl.