ÌRÒYÌN
Wọ́n Fi Wọ́n Sẹ́wọ̀n Torí Ohun Tí Wọ́n Gbà Gbọ́—Rọ́ṣíà
Wọ́n ń fi àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n ní Rọ́ṣíà torí ohun tí wọ́n gbà gbọ́. O lè mọ púpọ̀ sí i nípa àwọn tó wà lẹ́wọ̀n, a tún ní ibi tá a kọ orúkọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní ẹ̀wọ̀n sí.
Orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Gbógun Wọ Orílẹ̀-èdè Ukraine—Ṣé Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Ló Ń Ṣẹ?
Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ṣé Bíbélì sọ ibi táwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ yìí máa já sí?
ÌRÒYÌN
Ilé Ẹjọ́ ní Rọ́síà Kéde Pé Ìwé “Agbawèrèmẹ́sìn” Ni Bíbélì
Ilé Ẹjọ́ Ìlú Vyborg kéde pé ìwé ‘agbawèrèmẹ́sìn’ ni Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lédè Rọ́síà, ìyẹn Bíbélì táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tẹ̀ jáde lóríṣiríṣi èdè.