Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Tọ́kì

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Turkey

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—5,692

  • Iye àwọn ìjọ​—71

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—8,873

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—15,502

  • Iye èèyàn​—85,957,000

2016-10-06

TỌ́KÌ

Ilé Ẹjọ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ti Ilẹ̀ Yúróòpù Sọ Pé Ìjọba Orílẹ̀-èdè Turkey Gbọ́dọ̀ Fọwọ́ Sí I Pé “Ibi Ìjọsìn” Ni Gbọ̀ngàn Ìjọba

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìṣòro táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ní lábẹ́ òfin lórílẹ̀-èdè Turkey ti ń lójú díẹ̀díẹ̀, wọn ò tíì lè ní ilé ìjọsìn tiwọn tàbí kí wọ́n kọ́ ọ torí wọ́n ń ṣe ẹ̀tanú sí wọn.